OSACA ANTHEM
Osaca lẹgbẹ wa, ẹgbẹ́ olubori àwọn àgbẹ̀
Ohun wa, ìdúró wa, irọrun ni fún àwọn àgbè
Ikan parapọ̀ ìkan mole, eerun parapò won magiyan
Osaca Isokan àgbè
Fundagbasoke ipinle Ondo, ẹ jẹ kajo ṣe kó yẹ wá
Àwa ń dáàbò bo ilẹ̀ wa, kò le fún wa lérè púpọ̀
Oowo wa, iṣẹ́ẹ wa, ohun jíjẹ fún mutumuwa
Kamuse oko wa kó yanjú, kale f'ounje fún ìran èèyàn
Osaca Isokan Agbe
Fundagbasoke ise ogbin, Ẹ jẹ ká jọ ṣe kó yẹ wá
Ilẹ̀ olora n'ilẹ̀ wa, aridununun fún àwa agbe
Kagbin kowu, Karata, ìpèsè ìṣe fún àwọn èèyàn/Ọ̀pọ̀lọpọ̀
Amuse wa pelu Ìfẹ́, lojoojumo lanwa imọ kunmọ̀/Lola Oluwa ao ṣ'aseye
Osaca Isokan Agbe
Koro aje wa kóle sunwon, ẹ jẹ ká j'ọṣé kó yẹ wá